Taoreed Lagbaja
From Wikipedia, the free encyclopedia
Àdàkọ:Use Nigerian English
Quick Facts Major General, Chief of Army Staff ...
Major General Taoreed Lagbaja | |
---|---|
Chief of Army Staff | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 19 June 2023 | |
Ààrẹ | Bola Tinubu |
Asíwájú | Faruk Yahaya |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kejì 1968 (1968-02-28) (ọmọ ọdún 56) Irepodun, Western State, Nigeria (now in Osun State) |
Alma mater | |
Military service | |
Allegiance | Nigeria |
Branch/service | Nigerian Army |
Years of service | 1987–present |
Rank | Major general |
Close
Ọ̀gágun Major General Taoreed Abíọ́dún Lágbájá (ni wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 1968) jẹ́ Ọ̀gágun-àgbà tí ó gboyè Major General nínú iṣẹ́ ológun orílẹ̀ - èdè Nigeria. Òun ni Ọ̀gágun-àgbà yányán àwọn ológun Nigeria, Chief of Army Staff.[1][2][3] He was appointed on 19 June 2023 by President Bola Tinubu to succeed Lieutenant General Faruk Yahaya.