Bọ́lá Tinúbú
Olóṣèlú / From Wikipedia, the free encyclopedia
Bọ́lá Ahmed Tinúbú (ọjọ́ ìbí Ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù Kẹ́ta, ọdun 1952) jẹ́ Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nigeria tí wọ́n ṣe ìbúra fún lọ́jọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2023 lẹ́yìn tí ó jáwé olúborí nínú ìdìbò ààrẹ ọdun 2023.[1] Ó jẹ́ Gómìnà-àná Ìpínlẹ̀ Èkó láàrin ọdún 29 May odun 1999 títí di ọdún 29 May, 2007.[2] Àwọn ará ìlú ti kọ́kọ́ dìbò yàn Bola Ahmed Tinubu láti di Sẹ́nétọ̀ ní ọdún 1992, àmọ́ wọ́n fagilé ìbò náà ní ọdún (12 June, 1993)[3]
Quick Facts Bola Tinubu, 12th Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó ...
Bola Tinubu | |
---|---|
12th Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó | |
In office May 29, 1999 – May 29, 2007 | |
Asíwájú | Buba Marwa (military admin.) |
Arọ́pò | Babatunde Fashola |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 29 Oṣù Kẹta 1952 (1952-03-29) (ọmọ ọdún 72) Lagos State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressive Congress |
Occupation | Politician |
Close