Robert Greene (American author)
From Wikipedia, the free encyclopedia
Àdàkọ:Other people Àdàkọ:Use American English Àdàkọ:Use mdy dates Àdàkọ:Advert
Quick Facts Ọjọ́ ìbí, Iṣẹ́ ...
Robert Greene | |
---|---|
Ọjọ́ ìbí | 14 Oṣù Kàrún 1959 (1959-05-14) (ọmọ ọdún 64) Los Angeles, California, U.S. |
Iṣẹ́ | Author |
Notable works |
|
Partner | Anna Biller |
Close
Robert Greene (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrìnlá oṣù karùn-ún ọdún 1959) jẹ́ oǹkọ̀wé ọmọ Amẹ́ríkà tí ó kọ ìwé nípa strategy, power, àti seduction.[1][2] Ó ti kọ oríṣiríṣi ìwé tí wọ́n tà wàràwàrà káàkiri àgbáyé, lára wọn ni Òfin Méjìdínláàádọ́ta Agbára, The Art of Seduction, The 33 Strategies of War, The 50th Law (with rapper 50 Cent), Mastery, àti The Laws of Human Nature.[3]
Greene fìgbà kan sọ wípé òun kì í tẹ́lẹ̀ gbogbo ìmọ̀ràn tí wọ́n bá gba òun, wípé ẹnikẹ́ni tí ó bá gba òun ní ìmọ̀ràn lè banújẹ́ lọ́dọ̀ òun."[4]