Patrick Seubo Koshoni
Olóṣèlú / From Wikipedia, the free encyclopedia
Patrick Seubo Koshoni tàbí Patrick Sẹ́húbò Koshoni tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹrin ọdún 1943 tí ó sìn kú ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kìíní ọdún 2020 (April 17, 1943- 25 January, 2020) jẹ́ ajagun-fẹ̀yntì orí omi Nigerian Navy Vice Admiral,[1] ọ̀gágun yányán Chief of Naval Staff àti mínísítà-ana fún ìlera nígbà ìṣèjọba ológun Ààrẹ Muhammadu Buhari.[2] [3] Nígbà ìṣèjọba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí mínísítà-ana fún ètò ìlera, ó gbìyànjú láti ṣe ìdásẹ̀lé ètò Máàdámidófò lórí ìlera láìsí owó sísan kalẹ̀
Quick Facts Àdàkọ:BLP sources, Chief of Naval Staff ...
Àdàkọ:BLP sources | |
---|---|
Chief of Naval Staff | |
In office 1986–1990 | |
Asíwájú | Rear Adm. A. Aikhomu |
Arọ́pò | Vice Adm. M. Nyako |
Federal Minister of Employment, Labour and Productivity | |
In office 1985–1986 | |
Federal Minister of Health | |
In office December 1983 – August 1985 | |
Asíwájú | D.C Ugwu |
Arọ́pò | Olikoye Ransome-Kuti |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | (1943-04-17)Oṣù Kẹrin 17, 1943 Lagos |
Aláìsí | January 25, 2020(2020-01-25) (ọmọ ọdún 76) |
Alma mater | St Finbarr's College National Defence Academy |
Military service | |
Allegiance | Nigeria |
Branch/service | Nigerian Navy |
Years of service | 1962-1990 |
Rank | Vice Admiral |
Close