Ghezo
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ghezo, tí sípẹ́lì rẹ̀ tún jẹ́ Gezo, jẹ́ ọba ilẹ̀ Dahomey, (èyí tó ti di ìlú Benin báyìí) láti ọdụ́n1818 títí wọ 1859. Ghezo rọ́pò ẹ̀gbọ́n rẹ̀ tí ń jẹ́ Adandozan (tó jọba láti ọdún 1797 títí wọ ọdún 1818) gẹ́gẹ́ bí i ọba látàri ìsọ̀tè tó wáyé pẹ̀lú ìànlọ́wọ́ àwọn olówò ẹrú ilẹ̀ Brasil, ìyẹn Francisco Félix de Sousa. Ó jọba lóri ìlú náà lásìkò tí rúdurùdu gbilẹ̀ ní ilẹ̀ náà, pẹ̀lú ìdíwọ àwọn èbúté lóríṣiríṣi tó ti ọwọ́ àwọn aláwọ̀ funfun wá, láti dẹ́kun Atlantic slave trade.[1]
Quick Facts Reign, Predecessor ...
Ghezo | |
---|---|
King of Dahomey | |
A depiction of King Ghezo in a 1851 publication | |
Reign | 1818–1859 |
Predecessor | Adandozan |
Successor | Glele |
Father | Agonglo |
Died | 1859 (1860) |
Close
Ghezo ló fòpin sí sísan ìṣákọọ́lẹ̀ sí Oyo Empire.[2] It is quite likely that the initial struggle was more violent than this story relates.[3] Lẹ́yìn náà, ó gbógun ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ olówò ẹrú, ní ìbámu láti dẹ́kùn òwò náà. Wọ́n pa Ghezo ní ọdún 1859, ọmọ rè Glele sì jọba.