Asimina triloba
From Wikipedia, the free encyclopedia
Àdàkọ:Use mdy dates
Taxonomy not available for Asimina; please create it automated assistant
Asimina triloba | |
---|---|
In fruit | |
Ipò ìdasí | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ] | |
Irú: | Template:Taxonomy/AsiminaA. triloba |
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Template:Taxonomy/AsiminaAsimina triloba (L.) Dunal | |
Natural range |
Asimina triloba, ti amo ni ibepe òyìnbó , ibepe tabi ibeepe laarin awọn orukọ ti o wa ni igberiko, je igi kekere ti o tan mo eastern United States ati Canada, o sì nso eso ti o Tobi ti o sì ni awo ofeefe sí awo ewe.[3][4][5] Asimina je eya irúgbìn lati inu idile tropical ati subtropical flowering Annonaceae, Asimina triloba si je gbogi laarin wọn.[6] Awọn eso ti eya rẹ yato ti o sì jẹ gbajugbaja ninu idile Annonaceae jecustard-apple, cherimoya, sweetsop, ylang-ylang, ati soursop.
Ibepe yìí jé clonal understory igi ti igi igbó lile ti a le ri ninu Igbo ti a ti maan ri igi gedu ,a le ri ni ibi ti ile tẹju sí pelu hilly upland .[7] O ni ewe ti ko le rara,o si Tobi pẹlu tipsi ,o si ni awọn iwa irúgbìn Igbo ojo ti a mo ni geesi ni rainforest sí irú irúgbìn ti temperate rangi.[8] Ibepe je eso ti o se je juju ni ile United state.[9][10] (ti a o ba ka gourds, ti a mo sí ẹfọ dipo eso fún ilo kulinary ,Amoo ninu botani ,a mo won sì eso
Eso ibepe dun pelu kustard flavour ti o jọ ògèdè,mango tabi ọpẹ oyinbo. Won saba maan je ni rirọ sugbon a tun le fi se ìfẹ kreamu ati baked desserts. Besituni, eyin re,ewe ,eso ati irúgbìn re ni potenti neurotoxin annonacin.[11]