Aretha Franklin
From Wikipedia, the free encyclopedia
Aretha Louise Franklin (March 25, 1942 – August 16, 2018) je akorin, akowe-orin, osere, ateduuru, ati alakitiyan eto araalu ara Amerika.[2] Franklin bere si ni korin lati kekere ninu egbe akorin gospel ni ijo New Bethel Baptist Church ni Detroit, Michigan, nibi ti baba re C. L. Franklin ti je oluso-agutan. Nigba to di omo odun 18, o bere si ni korin to gbode. Awon orin re to gbajumo bi "Respect", "Chain of Fools", "Think", "(You Make Me Feel Like) A Natural Woman", "I Never Loved a Man (The Way I Love You)", ati "I Say a Little Prayer", so di akorin agba lagbaye, eyi to je ki o gbajumo bi Queen of Soul.
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Aláìsí ...
Aretha Franklin | |
---|---|
Franklin in 1968 | |
Ọjọ́ìbí | Aretha Louise Franklin (1942-03-25)Oṣù Kẹta 25, 1942 Memphis, Tennessee, U.S. |
Aláìsí | August 16, 2018(2018-08-16) (ọmọ ọdún 76) Detroit, Michigan, U.S. |
Resting place | Woodlawn Cemetery Detroit, Michigan |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1956 – 2018 |
Ọmọ ìlú | Detroit, Michigan |
Olólùfẹ́ |
|
Àwọn ọmọ | 4 |
Parent(s) |
|
Àwọn olùbátan |
|
Awards | see, list |
Musical career | |
Irú orin | |
Instruments |
|
Labels |
|
Website | [http:// Official website] |
Signature | |
Close
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |