Amitabh Bachchan
Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Indian / From Wikipedia, the free encyclopedia
Amitabh Bachchan (Àdàkọ:IPA-hi; orúkọ àbísọ Inquilaab Srivastava;[1] ní 11 October 1942[4]) ni òṣeré, olóòtú fílmù, atọ́kùn ètò tẹlifísàn, akọrin àti olóṣèlú ará Índíà. Ó kọ́kọ́ gbajùmọ̀ nígbà ìbẹrẹ̀ àwọn ọdún 1970 fún àwọn fílmù bíi Zanjeer, Deewaar àti Sholay.
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Orílẹ̀-èdè ...
Amitabh Bachchan | |
---|---|
Bachchan in November 2018 | |
Ọjọ́ìbí | Inquilaab Srivastava[1] 11 Oṣù Kẹ̀wá 1942 (1942-10-11) (ọmọ ọdún 81) Allahabad, United Provinces, British India (present-day Uttar Pradesh, India) |
Orílẹ̀-èdè | Indian |
Orúkọ míràn | Angry Young Man, Shahenshah of Bollywood, Star of the Millennium, and Big B |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Sherwood College, Nainital Kirori Mal College, Delhi University[2] |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1969–present |
Net worth | $400 million (2020)[3] |
Olólùfẹ́ | Jaya Bhaduri (m. 1973) |
Àwọn ọmọ |
|
Parents |
|
Ẹbí | See Bachchan family |
Awards | Full List |
Honours | Dadasaheb Phalke Award (2019) Padma Vibhushan (2015) Padma Bhushan (2001) Padma Shri |
Website | Official blog |
Signature | |
Close