Adolph Zukor
From Wikipedia, the free encyclopedia
Adolph Zukor ( /ˈzuːkər/; Àdàkọ:Lang-hu; ọjọ́ keje oṣù kíni ọdún 1873– ọjọ́ Kẹ̀wá oṣù kẹfà ọdún 1976)[1] jẹ́ òṣeré ọmọ orílẹ̀ èdè Hungary mọ́ Amẹ́ríkà tí ó gbajúmò gẹ́gẹ́ bi ọkàn lára àwọn mẹ́ta tí ó dá Paramount Pictures kalẹ̀.[2] Ó ṣe àgbéjáde The Prisoner of Zenda ní ọdún 1913.[3][4]
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Aláìsí ...
Adolph Zukor | |
---|---|
Zukor in 1922 | |
Ọjọ́ìbí | (1873-01-07)Oṣù Kínní 7, 1873 Ricse, Kingdom of Hungary, Austria-Hungary |
Aláìsí | June 10, 1976(1976-06-10) (ọmọ ọdún 103) Los Angeles, California, U.S. |
Resting place | Temple Israel Cemetery, Hastings-on-Hudson, New York |
Orúkọ míràn | Adolf Zuckery |
Iṣẹ́ | Film producer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1903–1959 |
Gbajúmọ̀ fún | One of the three founders of Paramount Pictures |
Olólùfẹ́ | Lottie Kaufman (m. 1897–1956) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Ẹbí | Marcus Loew (daughter’s father-in-law) |
Signature | |
Close