Ogun abẹ́lé
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ogun abẹ́lé jẹ́ ogun láàárín àwọn ẹgbẹ́ tó ṣètò láàárín ìpínlẹ̀ kan náà (tàbí orílẹ̀-èdè ). Èrò tí ẹgbẹ́ kan lé jẹ̀ẹ́ lá̀ti gba iṣàkóso orílẹ̀-èdè tàbí agbègbè kan, lá̀ti gba om̀inira fún agbègbè kan, tàbí láti yí àwọn ètò ìmúlò ìjọba padà. Òrò náà jẹ́ calque ti Latin bellum civile èyí tí a lò láti tọ́ka sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ogun abelé ti Roman Republic ni ọ̀rú́ndun 1st BC.
́Pupọ̀ jùlọ àwọn ogun abẹlé òde òní pẹ̀lú ìdásí nípasẹ̀ àwọn agbára tí ó wá láti ibi-bòmíràn. Ní ì́bamu si Patrick M. Regan nínú ì́we re Civil Wars and Foreign Powers (2000) nípa ìdá méjì nínú méta ti àwọn 138 intrastate rògbòdìyàn láàárin World War II èyí tí o ti ń súmọ́n ìparí rẹ̀ àti 2000 ri òkèrè intervention. [1]
Ogun abelé jẹ́ rògbòdìyàn-kíkankíkan kan, ní̀gbagbogbo pẹ̀́̀lu awọn ológun oló̀gun, eyí tí ó dúró,tí ó ṣètò àti tí ó wà ní ìwọ̀n-ńlá. Àwọn ogun abẹlé lé è já sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olùfaragbá̀ ati lílo àwọn orísun pàtàkì. [2]