Morris Chestnut
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America / From Wikipedia, the free encyclopedia
Morris L. Chestnut (ojoibi January 1, 1969) je osere filmu ati telifisan ara Amerika. O gbajumo fun isere re bi ewe to ti bimo, Ricky Baker ninu filmu odun 1991 Boyz n the Hood, bi oko to fe segbeyawo Lance Sullivan ninu filmu odun 1999 The Best Man, bi Tracy Reynolds, agbaboolu NBA ninu filmu odun 2002 Like Mike, ati bi Visitor Ryan ninu ere telifisan odun 2009 TV V.
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Iṣẹ́ ...
Close
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |