Kọ̀ríkúlọ́ọ̀mù
From Wikipedia, the free encyclopedia
Nínú ètò ẹ̀kọ́, Kọ̀ríkúlọ́ọ̀mù ni ó túmọ̀ sí pààpin kókó ètò-ẹ̀kọ́ nínú ìlànà ikọ́ni.[1][2] Ó tún lè jẹ́ àgbékalẹ̀ pàtó tí ó dá lé ìrírí àti òye àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fún ìkọ́ni tààrà..[3] Kọ̀ríkúlọ́ọ̀mù ma ń kó kókó iṣẹ́, ohun èlò ìkẹ́kọ́ àti ọ̀nà ìṣe ìgbéléwọ̀n fún ètò ìkẹ́kọ̀ọ́ náà.[4]
Ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ Curriculum vitae.