Adìyẹ
From Wikipedia, the free encyclopedia
Taxonomy not available for Gallus; please create it automated assistant
Gallus gallus domesticus | |
---|---|
A rooster (left) and hen (right) perching on a roost | |
Ipò ìdasí | |
Ọ̀sìn | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ] | |
Subgenus: | Template:Taxonomy/Gallus |
Irú: | Template:Taxonomy/GallusG. gallus |
Irú-ọmọ: | Template:Taxonomy/GallusG. g. domesticus |
Ìfúnlórúkọ mẹ́ta | |
Gallus gallus domesticus (Linnaeus, 1758) | |
Chicken distribution |
Adìyẹ (Gallus gallus domesticus) jẹ́ ẹ̀yà ẹyẹ àti ẹranko ilé tí a ń sìn ní ilé tí wọ́n sì pín sí ẹ̀yà oríṣiríṣi bíi; grey and the Ceylon junglefowl[1] tí a lè rí ní apá Southeastern Asia. A lè akọ adìyẹ ní akọ tàbí kí a pèé ní Àkùkọ yálà èyí tí ó ti dàgbà tàbí èyí ó ṣẹ̀sẹ̀ ń dàgbà bọ̀. Èyí tí ó jẹ́ abo ni a lè pe ní abo adìyẹ tàbí obí yálà èyí tí ó ti dàgbà tàbí èyí tí ó ń dàgbà bọ̀. Ìran ọmọnìyàn ń sin adìyẹ yálà abo tàbí akọ gẹ́gẹ́ bí ounjẹ yálà nípa jíjẹ ẹran wọn tàbí jíjẹ ẹyin tí wọ́n bá yé sílẹ̀.
Nínú gbogbo ẹranko tàbí ẹyẹ oko tabi ilé, adìyẹ ni wọ́n sábà ma ń sin jù gẹ́gẹ́ bí ohun ọ̀sìn jùlọ pẹ̀lú iye rẹ̀ tí tó 23.7 bílíọ́nù Àdàkọ:Ní àsìkò ọdún,[2] tí ó sì tún gbéra sọ sí bílíọ́nù mọ́kàndínlógún (19) ní ọdún 2011. Ẹyẹ adìyẹ ní ó pọ̀ jùlọ nínú ohun ọ̀sìn ilé ni gbogbo agbáyé bí ó ti jẹ́ wípé oríṣiríṣi ìgbàgbọ́ ni ẹ̀yà, ìtàn, ẹ̀sìn, èdè òun ìran orísiríṣi ní nípa sínsin adìyẹ gẹ́gẹ́ bí ohun ọ̀sìn.