A. Philip Randolph
Olóṣèlú / From Wikipedia, the free encyclopedia
Asa Philip Randolph (April 15, 1889 – May 16, 1979) jẹ́ alákitiyan ará Amẹ́ríkà tó jẹ́ asíwájú nínú ìrìnkánkán ẹ̀tọ́ aráàlú àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà, ìrìnkánkán ọ̀ṣìṣẹ́ Amẹ́ríkà àti àwọn ẹgbẹ́ olóṣèlú sósíálístì.
Quick Facts Philip Randolph, Ọjọ́ìbí ...
Philip Randolph | |
---|---|
A. Philip Randolph in 1963 | |
Ọjọ́ìbí | (1889-04-15)Oṣù Kẹrin 15, 1889 Crescent City, Florida |
Aláìsí | May 16, 1979(1979-05-16) (ọmọ ọdún 90) New York City |
Close
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |