Ẹran ìgbẹ́
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ẹran ìgbẹ́ túmọ̀ s'àwọn ẹran tí wọ́n pa ní inú igbó ó sì tún túmọ̀ sí àwọn ẹranko tí àwọn ènìyàn ń jẹ nínú igbó, pàá pàá jù lọ, ní ilẹ̀ Adáwọ̀. Ẹran ìgbẹ́ jẹ́ orísun amú purotéènì ara fún àwọn ènìyàn Latin Amẹ́ríkà àti Asia.[1] ó tún jé orísun oúnjẹ fún àwọn ẹlòmíràn, pàá pàá jùlo àwọn tálíkà ní ìgbèríko.[2] Jíjẹ ẹran ìgbé wà lára ohun tí ó le ṣokùnfà àìsàn ara bi Ebola virus àti HIV wá láti ara ẹran ìgbé.[3][4][5]
Quick Facts Alternative names, Main ingredients ...
wọ́n mo ń sábà fi ẹran ìgbé láti mó jẹ́ kí ó bà jẹ́ | |
Alternative names | Wild meat, wild game |
---|---|
Main ingredients | Wildlife |
|
Close