Átẹ́gùn Ooru
From Wikipedia, the free encyclopedia
Átẹ̀gun Óóru jẹ óóru to làgbàrà nigba óju ọjọ gbónà[1][2]. ọriniinitutu giga maa nwa pẹ̀lu Átẹ̀gun Óóru. Èyi maa nṣẹlẹ ni órilẹ edẹ pẹlù ójù ọjọ ókun[3].
Ìwọn Átẹgun óórù jẹ ìbàtàn fun ọju ọjọ àgbègbè ati deede otutu fun igba. Óóru lati àgbègbè awọ̀n eniyan to wa ni ójù ọjọ to gbóna jẹ Átẹgun óórù fun awọn ti oun gbè ni agbègbè to tutu. Èyi maa ṣẹlẹ ti gbìgbona otutu ba yatọ̀ si apẹrẹ ójù ọjọ fun àgbègbè naa[4]. Átẹgun óórù wọpọ to dẹ tun làgbàrà lori ilẹ kàkirì àgbègbè lati ọdun 1950s latari Àyipadà ójù ọjọ[5].
Átẹgun óórù to lagbara maa njasi bibajẹ ohun ọgbin, wọn si maa lèkun iná igbó ni awọn agbègbè ti ọgbẹ̀lẹ ti maa nṣẹlẹ[6][7]. Eyi maa jasi àyipada inà ijọba nitori imulètutu ti awọn èniyan ló.
Átẹgun óórù jẹ ójù ọjọ to làgbàrà eyi lo si ma fa èwù fun ilèrà awọn èniyan nitóri óóru ati óórun maa nbóri awọn ẹ̀yàeto itutu agbaiye ara eniyan[8]. Ó ṣèṣè latiri Átẹgun óórù pẹ̀lù awọn ìrìnṣẹ Àfojúsùn ojú ọjọ.