Àwọn ọlúgbé Áfríkà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìye àwọn olùgbé Áfríkà ní bi ọgọ́rùn-ún ọdún sẹ́yìn ti pọ̀ si pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ iye,[1] ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olùgbé yìí sì jẹ́ ọ̀dọ́, ara ìdí fún eléyìí ni pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn ní àwọn orílẹ̀ èdè kọ̀kan ní ilẹ̀ Áfríkà kìí dàgbà kọjá àádọ́ta ọdún .[2] Iye àwọn olùgbé ilẹ̀ Áfríkà ní ọdún 2020 tó bílíọ́nù kan lé ní ọ́ọ̀dúnrún ,mílíọ̀nù[3] tí iye àwọn olùgbé yìí sì ń dàgbà si pẹ̀lú 2.5% ní ọdọọdún.
Orílẹ̀-èdè tí ó ní àwọn olùgbé jù ni Nàìjíríà pẹ̀lú olùgbé tí ó lé ní igba mílíọ̀nù ní ọdún 2020.[4]