Àtòjọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Hàítì
ojúewé àtojọ Wikimedia / From Wikipedia, the free encyclopedia
Àyọkà yìí ṣe àtòjọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Hàítì láti ìbẹ̀rẹ̀ Ìjídìde àwọn ará Hàítì ní 1791. Òmìniran gangan jẹ́ fífilọ́lẹ̀ ní 1804.
Between 1806 and 1820 Haiti was divided between the northern State, renamed Kingdom of Haiti in 1811, and the southern Republic of Haiti. Between 1822 and 1844 the Republic of Haiti ruled over the entire island of Hispaniola, during the period known as the unification of Hispaniola.