Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Olómìnira Benin
From Wikipedia, the free encyclopedia
Àjàkálẹ̀ àrùn Ẹ̀rànkòrónà-19 tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí COVID-19 kọ́kọ́ bẹ́ sílẹ̀ ní Orílẹ̀-èdè Olómìnira Benin ní oṣù kẹta ọdún 2020.
Quick Facts Àrùn, Irú kòkòrò èràn ...
Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Olómìnira Benin | |
---|---|
Arákùnrin ará Benin kan tí ó wọ ìbòjú ìdáàbòbò fún àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Olómìnira Benin. | |
Àrùn | COVID-19 |
Irú kòkòrò èràn | SARS-CoV-2 |
Ibi | Orílẹ̀-èdè Olómìnira Benin |
Ìjásílẹ̀ àkọ́kọ́ | Wuhan, China |
Index case | Porto-Novo |
Arrival date | ọjọ́ kẹrìndínlógún ní oṣù kẹta ọdún 2020. 2020 (6 months, 2 weeks and 3 days) |
Gbogbo iye àwọn ẹ̀sùn | 1,124 (as of 27 June 2020)[1] |
Active cases | 815 (títí di ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 2020) |
Iye àwọn tí ara wọn ti yá | 295 ( títí di ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 2020)[1] |
Iye àwọn aláìsí | 14 (títí di ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 2020)[1] |
Official website | |
https://sante.gouv.bj/COVID19-TOUT-SAVOIR-SUR-LA-GESTION-DE-LA-PANDEMIE-AU-BENIN |
Close